MUSIC LYRICS

LYRICS: Ranti – Iwe Kiko (Music)

A unique and reminisce style of music Titled Iwe Kiko
(Education) by Ranti and Produced by the Talented Cobhams Asuquo. Find below complete Lyrics of the song brought to you by Update360ng.

Look out for the English subtitle, coming soon… Enjoy.

(MUSIC LYRICS) : RANTI – IWE KIKO PROD. BY COBHAMS ASUQUO

(PRELUDE/VERSE 1)

Iwe kiko lai si oko ati ada

Ko I pe ooh (ko I pe ooh)

Ise agbe ni ise ile wa

Eni kosi se a maa ja le

Iwe kiko lai si oko

Ati ada, ko I pe ooh (ko I pe ooh)

Ise agbe ni ise ile wa

Eni kosi se a maa ja le

(HOOK)

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

(VERSE 2)

Ishapa lai si iyan ati egusi

Ko I pe ooh (ko I pe ooh)

Iyan ati eba  l’ounje ile
wa

Eni ko je yan, a je eba to tutu

Ishapa lai si iyan ati egusi

Ko I pe ooh (ko I pe ooh)

Iyan ati eba  l’ounje ile
wa

Eni ko je yan, a je eba to tutu

(HOOK)

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

(BRIDGE)

Awon omo alai gboran, won de ile iwe

 Won ko f’eti sile s’ohun
t’oluko ko won

Oluko ni ko k’awe, won si ma sere ka

Won a jeun!jeun!jeun!!

Won gb’odo roboto

 (FINALE /HOOK)

Ise! Ise! Iyen kin se ti won

Ere!Ere! Ere sha nit i won

Dodo ati Rice, ko gbodo koja

Won a jeun!jeun!jeun!!

Won gb’odo roboto

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

(eeeh)!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

O… o… o…o… o…o…oh!!!

 (MUSIC LYRICS) : RANTI – IWE KIKO PROD. BY COBHAMS ASUQUO

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *