LYRICS: Chris Ajilo Ft. Banky W & Korede Sax- Eko (COMPLETE LYRICS)
EKO, (The Remix); Pa Chris Ajilo, featuring Baky W and Korede Sax. If you either love jazz music, or the evergreen Eko song, or Lagos, or oldies, or Chris Ajilo, or Korede Sax, or Banky W, or you happened to love them all; then am certain you’ll love this song. After some clicking and linking, we finally got our hands on the mp3; so, we have the lyrics all scored out for you. Check it out below.
NOTE: As we’re talking about nice songs on EKO (Lagos state), we will recommend you check out another song by a very talented upcoming Artiste that goes by the name AQOREEN. It’s a dope and danceable song about our same darling Lagos state; he titled it EKO (check out the LYRICS: Chris Ajillo -“Korede”).
[MUSIC LYRICS]: Chris Ajilo Ft. Banky W & Korede Sax- Eko
(PRELUDE- CHRIS AJILO)
[Tell us the story, please] Well; know, when I was
small, my mother never flogged me; [Really?];
but she always tell me- very careful. Ma a koja aye o.
[Okay; Okay]; You know [yeah].
So, when I came back from Europe in 1955; she
said- now that you’re back; Eko o gba gbere o.
O yato si t’o wa tele. Tori na, mo ‘won ara e o.
A lot of people come to Lagos, they want to make it.
You have to be very careful; there is an easy way to
make it, and there is a tougher way to make it.
(HOOK- BANKY W)
Yeye mi pe mi, so fun mi tele tele
Eko Akete; Ilu Ogbon; [eh]
T’o ba duro k’o so’ra, [ye, ye] fun oniyangi
Eko o gba gbere rara o
Te’ti k’o gbo; ehh
(CHORUS)
Eko o gba gbere [Eko o]
Eko o gba gbere [Eko o]
Eko o gba gbere rara o
Eko o gba gbere rara o, oh, ohh; ehh
Eko o gba gbere [Eko o]
Eko o gba gbere [Eko o]
Eko o gba gbere rara o [Rara o]
(VERSE 1- CHRIS AJILO)
Eko ti wa fun gbogbo eniyan, l’omode, at’agba
So’ra k’o to gbe’se, k’o ma yo gere.
Ibere ohun tuntun t’o dara. Eko baje ti
Eko Ile ti wa a ju u; Ilu Ogbon; Eko Ile
(HOOK- BANKY W)
Yeye mi pe mi, so fun mi tele tele [tele tele]
Eko Akete; Ilu Ogbon
T’o ba duro k’o so’ra, fun oniyangi
Eko o gba gbere rara o
Te’ti k’o gbo; ehh
(CHORUS)
Eko o gba gbere [Eko o]
Eko o gba gbere [Eko o]
Eko o gba gbere rara o
(VERSE 2- BANKY W)
So’ra e; ma a suegbe, k’o la’ju kale
Ma a nogere, ma a f’oju si’le
Rora se, k’o f’ara ba’le
Mo ni, so’ra e; ma a suegbe, k’o la’ju kale
Ma a nogere, ma a f’oju si’le
Rora se, k’o f’ara ba’le
L’okunrin, l’obirin- e gbera n’le
E dide, ma a s’ole- k’ojo to pe
Eko o ni gba-gba-ku-gba [laelae]
Eko ti o le di ‘baje
(VERSE 3 / HOOK- CHRIS AJILO)
Eyin omo, e gbo ohun ti obi n so
O se pataki
Yeye mi pe mi, so fun mi tele tele
Eko Akete; Ilu Ogbon
T’o ba duro k’o so’ra, fun oniyangi
Eko o gba gbere rara o
Rara o
(CHORUS)
Eko o gba gbere [RARA]
Eko o gba gbere [RARA]
Eko o gba gbere RARA o
(FINALE- BANKY W)
I actually have a Lagos song called- Lagos Party
that we did a few years ago. So, when they now
said, ohh; you know; they want me to jump on this song.
I, it was such an honour. Because, I feel like it’s different
generation, but we’ still celebrating, and telling the
people about Lagos. So, it’s a big deal for me and ‘am sure,
for you too’. [Yes, of course]. So, thank you very much Sir.