MUSIC LYRICS

LYRICS: Sola Allyson Ft. Adekunle Gold– “Alujanjankijan”

LYRICS: Sola Allyson Ft. Adekunle Gold– "Alujanjankijan"

Here is the accurate music lyrics to the track ‘Alujanjankijan’ by Sola Allyson, featuring Adekunle Gold. Stream and sing along below. The song is an adaptation of a popular Yoruba’s folk’s tale (Alo).

(Sola Allyson- CHORUS)

Iya, Iya ta’kun wa’le- Alujanjankijan

Iya, Iya ta’kun wa’le- Alujanjankijan

E ma f’omo s’ile fun’ya je- Alujanjankijan

Eni t’o bi’mo lo ye k’o w’omo- Alujanjankijan

(VERSE 1- Sola Allyson)

Ba mi n’omo mi, o ye k’o de’nu olomo

Oju merin lo n bi’mo, sugbon, igba oju li n w’omo

Omo t’a o ko, a gbe’le t’a ko ta

Omo t’a o to, a k’eso t’a ni ta

Omo n’igbeyin, omo l’ola, omo l’ola, omo n’iyi, omo l’ade

Omo l’ewa, omo l’eso oh ohhh

O da a, bi o da a- o le da a; o san, bi o san- a de san

Igboya at’adura ni o gba- yi o da ahhh

(Sola Allyson- CHORUS)

Iya, Iya ta’kun wa’le- Alujanjankijan

Iya, Iya ta’kun wa’le- Alujanjankijan

E ma f’omo s’ile fun’ya je- Alujanjankijan

Eni t’o bi’mo lo ye k’o w’omo e; e t’omo- Alujanjankijan

(VERSE 2- Adekunle Gold)

Ori fun wa l’omo’re bi i ti Samuel oh

Won ko Samu, o gb’eko oh, o si se’hun rere

If you spare the rod, you go spoil the child; I hope you know?

Train them with the love of God; abegi oh

Tori, alaigboran omo- asa ni

Agba o kunwo l’oju- asa ni

Agba o jo won l’oju oh- asa ni

Agba iya ni o da- asa ni

Alalugboran omo oh- omo ni

Won le d’eyan l’ola- omo ni

T’a ba to won daada o- omo ni

Won le d’eyan l’ola

(Adekunle Gold- CHORUS)

Iya, Iya ta’kun wa’le oh- Alujanjankijan

Iya, Iya ta’kun wa’le oh- Alujanjankijan

Eni t’o bi’mo lo ye k’o w’omo oh- Alujanjankijan

E ma f’omo s’ile fun’ya je oh- Alujanjankijan

(CHORUS- Sola Allyson)

Iya, Iya ta’kun wa’le oh ohh- Alujanjankijan

E ma f’omo s’ile fun’ya je ohh- Alujanjankijan

Eni t’o bi’mo e lo ye k’o w’omo e; e t’omo- Alujanjankijan

Iya, baba, t’akun wa’le- Alujanjankijan

(SOLA ALLYSON- Verse 3)

Kekere la ti n pe’ka iroko, t’o ba d’agba tan, ebo ni o ma gba

Ohun t’a ba fi s’ile l’ewure n gbe; k’ewure aye ma ma gbe wa l’omo lo

Omo t’a o ba to, ekun aye a gbe lo; k’ekun aye ma ma gbe wa l’omo lo

(CHORUS- SOLA & ADEKUNLE)

Iya, Iya ta’kun wa’le- Alujanjankijan

Iya, Iya ta’kun wa’le oh ohh oh oh- Alu jan jan jan jan jan jan jan

Iya, Iya taaaaaaaaaa [Alujanjankijan] ‘kun

Iya, Iya ta’kun wa’le oh- Alujanjankijan

(VERSE 4/FINALE- Adekunle Et Allyson)

Edumare, k’o ba wa t’omo wa oh- Alujanjankijan

Edumare, k’o ba wa t’omo wa oh

Children are the heritage of the Lord oh- Alujanjankijan

E gbo! Omo l’ola, omo l’aye [Alujanjankijan]; omo l’ewa

Omo l’ere, k’a f’aye s’ile, k’a t’omo wa ohh- Alujanjankijan

They are the future generation- Alujanjankijan

Iya, Iya ta’kun wa’le- Alujanjankijan

[LYRICS: Sola Allyson Ft. Adekunle Gold- “Alujanjankijan”]

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *