LYRICS: DJ Neptune x Larry Gaaga – “Shawa Shawa” Ft Olamide x CDQ x Slim Case
(SIGN IN)
<Connect mi mo DJ Neptune>
Mo r’ogo, mo daran; o ti je gbese
Mo r’ogo, mo daran
(HOOK)
Kesh wa; mi o rapa mi mo o- mi o rapa mi mo o
Bunba wa; mi o rese mi mo o- mi o rese mi mo o
(CHORUS)
Sawa sawa, sawa lelei- sawa sawa, sawa lelei
Oya, sawa sawa, sawa lelei- sawa sawa, sawa lelei
{Yea yea in the building}
{Woss wobi; ekuro lona}
(VERSE 1)
Mo fe pawo; owun emi na ki n chill pelu agba awo- yeba
Ko Ileke s’orun at’owo bi eni s’awo- Oloun
La sugar lat’aro titi di ile su
(CHORUS)
Oya, sawa sawa, sawa lelei- sawa sawa, sawa lelei
Oya, sawa sawa, sawa lelei- sawa sawa, sawa lelei
{Connect mi mo DJ Neptune}
(VERSE 2)
Se, iwo lo moro so?
Iwo lo wa lori Insta-Blog abi?
Eja Nla ti mo sana si- issa banger
Lo sori page mi- gbogbo won dagbana
Da duro bi ti Kiss Daniel- mi o kana
Oju t’o n le yen- ija lo ba n be o
Clinching lo n gba jo- o n se baller o
Ni VIP- ma lo d’orun le o
Bouncers pe 30- t’on ma ti e bo le o
Won ni lamba mi sare ju Tom Cruise lo
Iso idi mi- o n run ju Tom Ford lo
Orin- lamba; oro- lamba; ede- lamba
Watch your sister- o n ke (Sesami Ganja)
Kowope, kowole lomo- commercial
Mo yan nofila; mo tun ti yan sadaka
Mo se Muslim, mo se Christian; ko seunti- wa gba’mi
Lori ise mi; ibile titi
[Read Also]: LYRICS ENG. TRANSLATION: DJ Neptune & Co – “Shawa Shawa”
(CHORUS)
Sawa sawa, sawa lelei
Oya, sawa sawa, sawa lelei- hmm, update
(VERSE 3)
Won o r’iru e ri; o wuwo
O po l’eti; awon stubborn
Awon omo bebo; a rugged
9jalyrics.com.ng; Yebo Squad
Yeh; igboro; fi si one time
K’o wole one time; nanana
No dulling; lelele
Mo ma ti gbagbe ke; apa mi da?
Ese mi da? Ye; apa mi da?
Ye; ese mi da?
Ehh; sawa sawa sawa lelei
Oh my God; sawa lelei
Eja Shawa Shawa, Shawa lelei
Oh my God; Shawa lelei
Ki lo fun mi mu n Shrine?
It can say mee
Uhhh; arararara; grateness grateness
(SIGN OUT)
Ah ah, ah ah
Owo ojumo ni ko n se salary
O ti ye e?
Omo wobe o ni CV
Huu; DJ Neptune! Ah no; that’s my sister
Okay; watch e