MUSIC LYRICS

CDQ Featuring Pasuma – “Oga Nla” (MUSIC LYRICS)

CDQ Featuring Pasuma - "Oga Nla" (MUSIC LYRICS)

Oga Nla ni mo je
Omo Iyawo Anobi Alabi
Woss woss wobi, Won pe ee
La’ju e, t’o ba n sukun k’o ma r’iran
File, oshe, omo aye
CDQ yea yea, file

Oga Nla ni mo je

Bere mi ninu abete – Oga Nla ni mo je
Lekki de Mushin Oloosha – Oga Nla ni mo je
Saago, ki lo kan boss – Oga Nla ni mo je
Actor l’o n se wahala – Oga Nla ni mo je

Ehh bere mi ninu abete – Oga Nla ni mo je [Olohunn]
Lekki de Mushin Oloosha – Oga Nla ni mo je
MC, ki lo kan boss – Oga Nla ni mo je
[Ess ess ess, ma te’go mole, werey kuro nbe]
Actor l’o n se wahala – Oga Nla ni mo je
[Won pe eee], t’o ba be, o ma te [Olohun]
Swag bi eni t’egbe ndun but ara ni mo fi gbe [waa gba]

Rather be a king in the jungle than to be a dog in the city [Olohun Se]

These niggas wanna pull me back but o shock wan that I did it [I did it]
Packaging l’o fin disguise; all these rappers are fish pies
No godfather sugbon Olohun wa lori hustle yi, e sure me die
Mo Kunle Poly won [peww peww]
F’owo ko mi lorun ke [chill chill, gbaa]
Gbe keke e lo bi Covid-19 [ladugbo mi], mi o tan’a w’ebi – keep distance

Oga Nla ni mo je

Bere mi ninu abete – Oga Nla ni mo je
Lekki de Mushin Oloosha – Oga Nla ni mo je
Saago, ki lo kan boss – Oga Nla ni mo je
Actor l’o n se wahala – Oga Nla ni mo je

Ehh bere mi ninu abete – Oga Nla ni mo je [Olohunn]
Lekki de Mushin Oloosha – Oga Nla ni mo je
MC, ki lo kan boss – Oga Nla ni mo je
Actor l’o n se wahala – Oga Nla ni mo je

Oga Nla ni mo je

Mo je; omo igboro gan je
Won ti n gbo lati 80s, 90s – okay
Awon Gen Z gan n je – won je
Awa kan fine ni, stainless – stainless
T’an ba gbemu, e le won pelu stainless
Omo eyan kan ni watch ni o [watch], eje, seb’Oluwa lo ni timing
Certified bag l’awa nbi; storymack end time ahh
Oluwa loni banging [banging]

Ma so p’o gbo o, ma so p’o gba o
Eyan mi, ma so p’o gbo o, ma so p’o gba o
Oga Nla ni wa lekun Iya Ajibola

Oga Nla ni mo je

Bere mi ninu abete – Oga Nla ni mo je
Lekki de Mushin Oloosha – Oga Nla ni mo je
Saago, ki lo kan boss – Oga Nla ni mo je
Actor l’o n se wahala – Oga Nla ni mo je

Ehh bere mi ninu abete – Oga Nla ni mo je [Olohunn]
Lekki de Mushin Oloosha – Oga Nla ni mo je
MC, ki lo kan boss – Oga Nla ni mo je
Actor l’o n se wahala – Oga Nla ni mo je

Kini bolo, keji bolo, panbolo kunbokun

Maa bo nani, je a bo lekan [Oga Nla ni mo je]
Aa bo nani – Paso
CDQ je ‘on mo je ‘on mo…
Master!

CDQ Featuring Pasuma – “Oga Nla” (MUSIC LYRICS)

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *