GOSPEL LYRICS

ACCURATE LYRICS: BisiManuel – “Aanu Ni”

GOSPEL LYRICS: BisiManuel - "Aanu Ni"

Ohun t’awon kan gb’awe fun, l’o se were
Omi ti won ni ko le san, t’o wa d’ibu
Mo ni b’o se n s’ola re o, ohun l’oye
Anu ni o, Aanu Ni

A se iru emi le j’oba

Owi ninu oro re, mo gba be
A se ireti tun wa fun gi agelori
O boro re mu, mo gba be
Omi odo to kan d’ele pada dun
Gege bi oro re, mo gba be
Anu ni ih, Aanu Ni ih eh

Ohun t’awon kan gb’awe fun
L’o se were [l’o se were]
Omi ti won ni ko le san, t’o wa d’ibu
[Eh, mo ni b’o se n s’ola o]
Mo ni bo se n s’ola re o [mo ni b’o se n pin’re]
Oun loye, [b’o se n f’omo ologo lo, ohun nika l’oye] Anu ni oo
[Mo l’anu ni], Aanu Ni [mo l’anu ni]

T’o ba je’le mo ti wa, ko le kan mi

Won ni no be hin turn, owo yen so wipe kan gbe fun mi
Ere asapojude ti gbogbo won sa de f’ori mi
Aide mo’wa wu mi o ku da’se Olorun duro
Ko da’se Olorun duro o
I was barely whispering your name
Didn’t even know the words to say
But somehow doors just opened up for me
Like you were waiting where I’d be
And I don’t understand it; thats the flavour of mercy
Yeh ih ihhh

[DON’T MISS]: Aanu Ni Lyrics English Translation

Ohun t’awon kan gb’awe fun [t’on gb’awe fun o]

L’o se were [l’o se were, l’o se were o]
Omi ti won ni ko le san, to wa di ibu
[He’ll make a way where there’s no way]
Mo ni bo se n s’ola re o [b’o se n s’ola]
Oun loye [mo ni b’o se n s’ola o]
Anu ni [mo ni Anuuu], Aanu Ni

ACCURATE LYRICS: BisiManuel – “Aanu Ni”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *